12/05/2016

K1, Osupa, Pasuma, Obesere, Malaika Tun Wo Gau Lodo Awon Alfa!



Igbimo awon alfa ti tun soko oro si awon irawo olorin fuji ti won n pe rawon loruko orisiri lagbole fuji. 

Alfa nla kan lo fi esun kan awon olorin fuji yii ni dede asiko to n salaye nkan ti Quaran alaponle so ni pa orin kiko. Alfa nla yii fi di re mu le pe, looto ni iwe mimo ti Musulumi fa ra mo orin sugbon irufe orin bee lati je orin ti o se awon eniyan ni anfani ni bi isin Olorun.
Otesiwaju pelu apeere bi won se forin ye Anobi si nigba ti o pada wolu Mekka Modinna lodun naa. Alfa yii ni iyalenu lo je pe opolopo awon olorin ile yoruba ko fi orin se ti Olorun, agaaga awon olorin fuji. O ni kakaki won forin gbe Olorun ga, iko kuko pelu oruko ti ko ye ki won pe rawon ni won je.
Ninu oro re, o ju bombuu nla ba awon irawo fuji bi Wasiu Ayinde to n pe arare ni Oluaye, Malaika toun naa nje Alayelua, Saheed Osupa to oun naa fira re je Oba nla. Baba yii ni ko enikeni to to pe ara re ni awon oruko wonyi bi ki ba nse Olorun Oba.
Geele bo se so, “ko si anfani ninu ki eniyan maa korin, ko fi ara re we Olorun tabi ko so ara ni oruko orisa bi arabambi, Alayelua, Oluaye, Oba nla bi awon olorin fuji se n pe arawon”


Credit: alafeonline

No comments:

Post a Comment

Nigeria Air: EFCC arrests Sirika over alleged N8bn fraud

  The Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) has picked up ex-Minister of Aviation, Hadi Sirika, over an ongoing N8,069,176,864.00 ...