07/02/2017

IMORAN FUN ESABOD LATI CELESTIAL MOTHER DORCAS-CCC

Image may contain: 1 person, eyeglasses and closeup
Oba mi oke nkan soso ti nse ohun ti enikeni Kankan ko le se, Oruko re ti ni iyin to ni gbo gbo orile ede aye ati ni oke orun
Note: either anybody likes it or not the spiritual will always supersede the physical realm – eleyi to tun mo si wipe emimimo ni agba oju baba nla baba, baba, baba, tobi gbogbo araye lomo lo.
Ni tori wipe omo emi ni emi se, ko ki nse nipa Agbara mi sugbon nipa ori-ofe Jesu ni
Eru oso kobami, eru aje kobami, motibo pata pata moti bo rau rau, motibo bolowo aye: ma se beru omo ijo mimo ma se beru oso, ma se beru omo ijo mimo, ma se beru aje.
Moni ayo pupopupo ninu Jesu to fun mi ni ore-ofe (in my life time) latifi oju mi ri awon iranse re wonyi to tun ran pada wa si orile aye yi.

Ti a banso nipa (falling angels) gege bi awon alaimokan ti nso tin so kiri, baba darijin won. Nitori won ko mo ohun ti won so mama wa esabod kin nse (falling angels) rara ati rara- ara awon eni ami ororo Olorun ni aye igbani ni mama esabod je fun eniti Olorun basi ni oju emi. Yio ri eleyi daju daju Ejeki adupe fun oro iye eyi ni iwe mimo Bibeli (Bible) ti afi fun wa lati fun wa ni ogbon, imon, oye, nipa ti to bi Agbara Olorun tosi ntoka si ohun gbogbo ninu aye yi ati ni oke orun. (because there can never never be any mistake in the work of God). Eyi ti babawa ninu Oluwa je okan ninu won (Rev. Pst. Founder S.B.J Oshofa) ako ti bi mi si aye yi nigbati aso won ni oruko yi (Samuel) Okan ninu awon eni ami ororo Olorun igbani ni won se (atunranwon pada wa si aye yi).
Bakan na ni baba wa (mose orimolade tun olase) okan ninu awon eni ami ororo Olorun ni won se atun ron won pada wa si nu aye yi (Moses) .Image may contain: 1 person
Ti o tun fi wa kan mama wa yi mama rere esabod ayaba ti afi ade oba de lori awon ni oba mi oke olori aye gbogbo lo ni aye igbani lati gba awon omo (Judah) sile kuro ninu igbekun oso ati aje eyiti (modekai) je okan ninu awon omo Judah.
Eni ami ororo Olorun igbani ni won se (Hadassa- Esther) atun ron won pada wa si aye yi lati wa gbawa kale kuro ninu igbekun awon aje ati oso aye yi ni.
ORINYI FUN MAMA WA DADA ADETOKUNBO ESTHER ABODERIN AYABA
1. Eni to Olorun fe lo lorun yan o, ka aje, oso mama binu mo.
2. Mama Esther kale san wa ju owuro lo o baba ibere lawa baba maje ka pofo.
3. Foro wa ru ota wa loju, oba oke ko lo mama Esabod lati mafi oro wa ru oso, aje, loju.
Ma please I want to be an agent of Esabod herbs and roots and the spiritual items here in Nigeria about foreign exchange there is no problem

No comments:

Post a Comment

NICE ONE: EFCC to arraign Cubana Chief Priest for Naira abuse

  The Economic and Financial Crimes Commission (EFCC) has filed a three-count charge against popular Instagram celebrity Pascal Okechukwu, a...