Ajimọbi: Pé Ayefẹlẹ Jẹ́ Àkàndá Kò Fún Láṣẹ Láti Rú Òfin
Gomina ipinlẹ Abiọla Ajimọbi ti sọ wi pe ohun yoo wa nnkan ṣe si ọrọ
ileeṣẹ gbajugbaja onkọrin Yinka Ayefẹlẹ eleyi to ti di orisun awuyewuye
bayii lẹyin ti ijọba wo ile naa ni owurọ ọjọ aiku.
Ninu ọrọ kan to ba awon oniroyin sọ lẹyin to kirun ọdun ileya tan ni yidi ilu Ibadan ni gomina Ajimọbi ti sọ ọrọ yii.
O ni ko si ẹni to tayọ ofin bi o ti wu ki ipo ti ẹni bẹẹ ba wa ṣe lee ri.
Gomina Ajimọbi ni ni iwoye ti oun, ibi ileeṣẹ Ayefẹlẹ wa ko ba ofin
mu ati pe awawi ni ohun ti awọn kan n sọ kiri pe akanda ẹda ni o si n
gba ọpọlọpọ eeyan siṣẹ.
Gomina ipinlẹ Ọyọ fi ọrọ rẹ we adigunjale to n ṣiṣẹ koto ni.
“Ṣe awọn adigunjale naa ko gba eeyan siṣẹ ni abi ka sọ pe tori pe wọn gba awọn eeyan si ẹnu iṣẹ ka fi wọn silẹ.”
Portable’s fourth begs God not to separate them with untimely death The fourth wife of singer Habeeb Okikiola, popularly known as Portabl...
-
A Prostitute Zainab ran away from Libya to Germany because her ex-partner Zaccehus asked for his 2 children's DNA she had for him in 2...
-
A mother has been left devastated after her son committed suicide on livestream and she walked in to see his dead body. The 18-year-ol...
-
The name Esabod is a household name. The name came from the names of Madam Esther Tokunbo Aboderin. She was born in Ibadan in the...